Monday, 14 May 2018

Ola ft. Adeyinka Alaseyori - Atobiju Lyrics

Welcome to MyWordLife Lyrics section.


You are viewing Ola ft. Adeyinka Alaseyori - Atobiju Lyrics. Download the audio by clicking the download button at the bottom of this page.


Be blessed as you sing along.


Ola ft. Adeyinka Alaseyori - Atobiju Lyrics








//contextual.media.net/nmedianet.js?cid=8CU5GFK35

Chorus
Olorun wa,
Ayeraye mo gbe o ga o
Mimo mimo Atobiju
Eyin nikan l’ogo ola ye fun


Verse 1 – Ola
From the rising of the sun
Unto it’s going down
Mi o r’eni to jo o
Ti mole fi o we
Ologo ara nla, t’oni gbogbo ogo
Ashiwere wipe, Olorun k’osi
N’oje ba won so, Nitori moti mo o
Olola Ni JESU mi, ewa re k’oja oye
Baba o ni bebe, sa ma t’oju mi lo
Olorun Baba Agba Oye.


Chorus
Olorun wa,
Ayeraye mo gbe o ga o
Mimo mimo Atobiju
Eyin nikan l’ogo ola ye fun


Adeyinka o ya now


Verse 2 – Adeyinka Alaseyori
Iyin re o le dawo duro, lenu MI Oluwa
Iba re Akoda Aye, Aseda l’ode orun
Asaju Ogun la lo, Akehin Ogun l’oje
Paripari Ola, Alebe ilu a sasi
O da wa si,
O pa wa mo
Olore e e e
Iwonikan l’awa gbe ga
Iwonikan l’awa pe bo
From the beginning of our lives
Till this very moment
Eh Eh Eh, You’ve been faithful
Ever faithful God


Chorus
Olorun wa,
Ayeraye mo gbe o ga o
Mimo mimo Atobiju
Eyin nikan l’ogo ola ye fun


Drums Interlude


Bridge
Call: E ba n’kira, E ba n’kira, E ba n’kira fun
Response: E ba n’kira 3x


Olori Aye gbogbo – E ba n’kira fun
T’omu riri jade ninu airi – E ba n’kira fun
Orisun Ayomi l’oje – E ba n’kira fun
O ni ole ojo merin dide Baba – E ba n’kira fun


O mu omi jade lati inu apata – E ba n’kira fun
O rin Lori omi, sibe ko ri – E ba n’kira fun
Ake to bo sinu omi, igi lofi gbe jade – E ba n’kira fun
JESU Olugbala o wo odi Jericho – E ba n’kira fun


Talaka wa Lo jeun pelu awon Oba – E ba n’kira fun
Ari na Ari Lo wa di ohun igbagbe – E ba n’kira fun
Agan ojo pipe, won di Iya olomo – E ba n’kira fun
K’osi ohun to s’oro se fun Olorun Bami – E ba n’kira fun


Ah Ah ATOBIJU
E ba n’kira fun.

//contextual.media.net/nmedianet.js?cid=8CU5GFK35

[button color="black" size="big" link="https://my.notjustok.com/track/download/id/298501" icon="fa-download" target="true"]DOWNLOAD MUSIC[/button]


Thank you for viewing Ola ft. Adeyinka Alaseyori - Atobiju Lyrics. Check out more gospel music lyrics in our Lyrics section.

No comments:

Post a Comment